Nairobi Railway Museum jẹ́ musíọ́mù rélíwè kan ní Nairobi, orílẹ̀ èdè Kenya, ní ẹgbẹ́ Nairobi railway station. Ó jẹ́ ilé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ère láti East African Railways tí ó daṣẹ́ sílẹ̀, East African Railways àti Harbours Corporation ni ó da kalẹ̀ ní ọdún 1971. Ó sì wà lábẹ́ ìdarí Kenya Railways.[1]

Nairobi Railway Museum
KUR 87 Karamoja at the Museum
KUR 87 Karamoja ní Nairobi Railway Museum
Lua error in Module:Location_map at line 464: Unable to find the specified location map definition. Neither "Module:Location map/data/Nairobi" nor "Template:Location map Nairobi" exists.
Building
Location
  • Station Road
  • 00200 Nairobi
  • Kenya
OwnerKenya Railways Corporation
Coordinates1°17′35″S 36°49′21″E / 1.29306°S 36.82250°E / -1.29306; 36.82250Coordinates: 1°17′35″S 36°49′21″E / 1.29306°S 36.82250°E / -1.29306; 36.82250
Ara àwọn ǹkan tí ó wà ní Musíọ́mù náà.

Ara àwọn ǹkan tí wọ́n kọ́kọ́ kó sí musíọ́mù náà ni àwọn ìjọ̀kó àwọn ọkọ̀ ayé àtijó tí kò. Ẹgbẹ́ẹ Friends of the Railway Museum East Africa (FORM East Afi[[Friends of the Railway Museum East Africa|ṣe ìrànlọ́wọ́ fún musíọ́mù náà láti wá àwọn ǹkan tí ó wà níbẹ̀ lónìí.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Wall, Graeme (30 October 2009). "Nairobi Railway Museum". Greywall. Greywall Productions. Retrieved 13 February 2010.