Nana Asantewaa
Nana Asantewaa jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù lóbìnrin ilẹ̀ Ghana tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù Kejìlá, ọdún 1993 28 December, 1993. Agbá-bọ́ọ̀lù náà múlé fún Police Accra gẹ́gẹ́ bi aṣọ́lẹ́ goalkeeper [1][2].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 28 Oṣù Kejìlá 1993 | ||
Playing position | Goalkeeper (association football) | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Police Accra | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |