Nana Gichuru
Ephex Kanana Gichuru (ti abi ni ojo kerinla osu kejila odun 1986)[1][2]je osere ati olugbalejo ori telifiosnu omo ilu Kenya. Awon eyan tun mo si Nana Gichuru.[3] Gege bii osere pje gbajumo fun awon ipa re ninu awon jara telifisionu Noose of Gold, Demigods atiHow to Find a Husband.[4] Gegebi olugbalejo ori afefe, oye ki ogbe eto Interior Designs jade, ki oto se alaisi. Otun sise pelu Kenya Airways. O se igbeyawo pelu RIchard Wainaina.
Nana Gichuru | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ephex Kanana Gichuru 14 Oṣù Kejìlá 1986 Nairobi, Kenya |
Aláìsí | 22 September 2015 Thika Road,Nairobi Eastern Bypass, Utawala | (ọmọ ọdún 28)
Orílẹ̀-èdè | Kenyan |
Orúkọ míràn | Nana Gichuru Wainaina |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2009 – 15 |
Website | nanagichuru.com |
IseÀtúnṣe
Gichuru ti kopa ninu orisirisi igbe jade gege bi Noose of Gold ni odun 2010 ati Demigods ni odun 2011. Eyi to je titun ninu awon eto re ni How to Find a Husband ati eto Interior Designs.
IkuÀtúnṣe
Ni gede ago mewa aro ni ojo kejilelogun osu kesan odun 2015, Nana ririn ajo ninu oko BMW e ni opopona fori nigba ti oko re lo kolu oko nla. Oku ni esekese, oku ni omo odun mejidinlogbon.[5]Iku e waye ni ojo mewa lehin igba ti o se asotele iku e lori ero aye lujara.[6][7] Won se eto iranti e ni ojo kedogbon osu kesan odun 2015 ni ile ijosin ijo methodist titi Rukaka.[8] Won sin ni ojo keji osu kewa odun 2015 ni ilu e Kaaga ni Meru.
Awon asayan ereÀtúnṣe
Odun | Akori | Ipa | Akiyesi | Netiwooki |
---|---|---|---|---|
2010– | Noose of Gold | Felma | olukopa akoko | NTV |
2011–12 | Demigods | Juliana | olukopa akoko | |
2015 | How to Find a Husband | olukopa akoko | Maisha Magic East | |
Interior Designs | Host | oye ki odari eto na ki oto se alaisi. | NTV |
Awon ItokasiÀtúnṣe
- ↑ "Nana Gichuru's birthdaty". Heka Heka. Retrieved 14 December 2015.
- ↑ "The memorial service for actress and Kenya Airways crew member 28-year-old Kanana (Nana) Gichuru was held on Wednesday September 30, 2015 at Ruaraka Methodist Church in Nairobi". Tuko. Retrieved 14 December 2015.
- ↑ "Nana Gichuru's biography". actors.co.ke. Retrieved October 29, 2015.
- ↑ "Nana Gichuru films". Actors.co.ke. Retrieved 14 December 2014.
- ↑ "Revealed: Actress Nana Gichuru's final moments before tragic accident". sde. Retrieved 14 December 2015.
- ↑ Kamau, Richard (23 September 2015). "She Drove Super fast, Predicted Her Death and Died Yesterday.. The SHOCKING Story of Nana Gichuru". Nairobi Wire. Retrieved 14 December 2015.
- ↑ "Kenyan actress predicts own death, dies a day after". My Joy Online. Retrieved 14 December 2015.
- ↑ Cynthia, Madame (30 September 2015). "The Late Actress Nana Gichuru’s Memorial Service". Mpasho. Retrieved 14 December 2015.