Nana Amma Gyamfuah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ kẹrin, óṣu August ni ọdun 1978. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbọrin postal gẹgẹbi forward[1].

Nana Gyamfuah
Personal information
OrúkọNana Amma Gyamfuah
Ọjọ́ ìbí4 Oṣù Kẹjọ 1978 (1978-08-04) (ọmọ ọdún 46)
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Postal Ladies
National team
Ghana women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 19 June 1999 (before the 1999 FIFA Women's World Cup)

Àṣèyọri

àtúnṣe
  • Nana kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 1999[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://fbref.com/en/players/6435ea17/Nana-Gyamfuah
  2. https://int.soccerway.com/players/nana-gyamfuah/291414/