Nana Hill Kagga Macpherson ti atun mo si 'Nana Kagga-Hill tabi 'Nana Hill' je omo orile ede Ùgándà, oje osere, ako ere, onimo ero ati agboroso iwuri.[1] O je gbajumo fun ise e ninu The Life, Beneath The Lies - The Series gegbi ako ere ati agbe ere jade pataki ati gege bi osere ninu Star Trek.,[2][3]

Nana Kagga Macpherson
RealTVfilms se iforo wani lenuwo fun Nana Hill Kagga ni odun 2008.
Ọjọ́ìbíNana Kagale Kagga
6 Oṣù Kẹrin 1979 (1979-04-06) (ọmọ ọdún 45)
Uganda
Ọmọ orílẹ̀-èdèUgandan
Iléẹ̀kọ́ gíga
  • University of Birmingham, United Kingdom
  • Redmaids' High School, Bristol United Kingdom
  • Gayaza High School, Uganda
  • Kampala Parents School, Uganda
Iṣẹ́
  • onkowe
  • Oludari
  • Osere
  • Elero epo
  • Agbọrọsọ iwuri
Ìgbà iṣẹ́2003–titi di asiko yi
Àwọn ọmọ3
Àwọn olùbátanawon omo iya marun

Oje okan ninu awon adajo Miss Uganda ni odun 2018.[4]

A bi Kagga si ilu Nairobi, Kenya fun awon obi ti o wa lati Uganda, kan ninu awon obi re je onimo ero. Kagga je Muganda, otun je omoba birin ni awon eya Baganda. Kagga je omo eleketa ninu omo mefa ti awon obi e bi. Ni asiko ti won bi, awon obi e wa lehin odi, ni asiko Oludari Idi Amin Kagga dagba si ebi olola. Yato fun baba ati baba-baba e, awon omo iya e merin na je onimo ero. Ilu Kampala ni Kagga n gbe pelu awon e meta. O gbo ede geesi ati ede Luganda.

Kagga pari ile eko alakobere ni Kampala Parents School. O darapo mo Gayaza High School, ile eko awon omo obinrin fun O-levels. O se A-levels ni Red Maids School, Bristol, ile eko awon omo ibinrin ti o ti dagba ju ni UK. Kagga loai il eko giga University of Birmingham, Birmingham, UK, ni ibi yi ni oti ko eko imo ero nipase titi epo robi. ni asiko isimi o ma n lo si Uganda lati se adari eto Jam Agenda lori WBS.[5]

Lehin ti o pari ile eko giga, Kagga ko lo ilu Florida ni ile USA, lehin igbana otun losi New Mexico ni Ilu Amẹ́ríkà. O sise ni ile ise Laguna gegebi oni mo ero ni Laguna nigba ti won sise pelu awon ologun.[6]

Hollywood (gege bi Nana Hill)

àtúnṣe

Kagga gbero lati se ise osere ni ilu Los Angeles osi ni awon aseyori kankan. Kagga kopa ninu awon ere Cowboys and Indians, A Good Day to Be Black and Sexy (Segment ‘Reprise’), He's Just Not That into You, Star Trek, CSI: NY – Boo, Life, Runway Stars. Ninu ere itage titi Amerika, Kagga ko ipa Mercy ninu ere Butterflies of Uganda ti Darren Dahms se, won yan ere na fun ami eye NAACP. Kagga ti kopa ninu opolopo fidio orin lati owo awon olorin bi P!nk, Amy Winehouse, Sting, Lenny Kravitz.[7] Kagga ti ko ipa ninu ipolowo orisirisi fun awon ilese KFC, Coors Light, Pepsi, DSW, Microsoft, APPLE, Tylenol, DOVE.[8] Ni igba ti owa ni ilu Amerika, Kagga ni ile itaja fun awon nkan ti oti pe ti osi ni iyi ni Santa Monica ti o pe ni A Vintage Affair.

Ni Uganda

àtúnṣe

Kagga pada si ilu Uganda ni odun 2009, o da ile ise sile ti oje Savannah MOON Ltd. Savannah MOOD labe akoso, Savannah MOON Productions won se agbejade ere The Life[9] ti won se afi han e ninu M-NET, jara telifisonu Beneath The Lies - The Series,[10]lowolowo bayi won se afihan e lori Urban TV ati MTN Uganda, How We See It. Savannah MOON tun gbe ere kan ti won pe akole e ni The Last Breath pelu Kampala Film School. Savannah MOON sise orisirisi lowo, ikan ninu e ni Taking Time, jara telifisonu ti on bo lona. Kagga da egbe kan si le You Are Limitless (YAL) o da si le ki oba le je nkan ti oma mu ori awon omo Afrika wu, ki won ba le se gbogbo nkan ti won fe se laye. Kagga tun sise pelu ile epo robi nla kan ni ilu Uganda.

Asayan Ere

àtúnṣe

Gegebi osere

àtúnṣe
Odun Fiimu Ipa Oludrai Akiyesi
2009 Star Trek Egbe atuko egbe J.J. Abrams Paramount Pictures
He's Just Not That into You Alejo inawo Ken Kwapis Universal Pictures
2008 A Good Day to Be Black and Sexy (Segment Reprise) Candi Dennis Dortch Magnolia Pictures
2007 Collision Fiimu adase
Hitch-hike Fiimu adase
Cowboys and Indians omo India Fiimu kukuru

Telifisonu

àtúnṣe
Odun Akori Ipa Oludari Akiyesi
2014 Beneath The Lies - The Series Adajo agba Joseph Katsha Kyasi Jara telifisonu Savannah MOON Productions
2008 Runway Stars Angeli Jara aye lujara
Life (NBC TV series) omo dudu awelewa Jara telifisonu, NBC
2007 CSI: NY – Boo Josephine Delacroix Joe Dante jara telifisonu, CBS
2006 BET Stars BET

Ere Itage

àtúnṣe
Odun Akori Ipa Adari Itage Akiyesi
2008 Butterflies of Uganda[11] Mercy[12] Darren Dahms Mercy Greenway Theater osu kesan si osu kewa odun 2008

Gegebi Atuko egbe

àtúnṣe
Year Film/TV Series Role Notes
Mela oludari jara ayelujara
2018 Reflections[13] Oludasile, oludari jara telifisonu pelu Cleopatra Koheirwe, Gladys Oyenbot, ati Housen Mushema
2016 The Last Breath alase o nse fiimu kukuru
2014 Beneath The Lies - The Series[14] alase o nse Jara telifisonu
How We See It agbalejo, oludari eto ejo titi Uganda
2012 The Life Oludari fiimu

Awon Itokasi

àtúnṣe
  1. "Star Profile: Nana Kagga An All Round Dreamer Changing The Face Of Television". Chano 8. Roy Ruva. Archived from the original on 19 October 2020. Retrieved 16 June 2016. 
  2. "Nana Kagga parades boo". Kampala Sun. Archived from the original on 8 May 2015. https://web.archive.org/web/20150508041357/http://kampalasun.co.ug/nana-kagga-parades-boo/. Retrieved 27 April 2015. 
  3. "New star studded TV series to hit screens in 8 weeks". Satisfaction Ug. http://www.satisfashionug.com/new-star-studded-tv-series-to-hit-screens-in-8-weeks/. Retrieved 30 July 2014. 
  4. "Five Miss Uganda beauty pageant judges unveiled". Uganda Online. Archived from the original on 18 October 2020. Retrieved 6 July 2018. 
  5. Baranga, Samson. "Kagga, the engineer with a passion for film". The Observer. Archived from the original on 28 August 2016. Retrieved 27 September 2012. 
  6. "Caught between the arts and sciences". Daily Monitor. Retrieved 28 August 2011. 
  7. "Interview with Nana Kagga of ‘The Life’". Mawado. Retrieved 9 August 2013. 
  8. ""If You Give Yourself Permission to Dream, You Will Be Amazed at What You Can Achieve" Nana Kagga-Macpherson #AfricanWomanOfTheWeek". Bugisi Ruux. Retrieved 3 August 2015. 
  9. "THE LIFE Official Movie Trailer, Directed by Nana Hill Kagga". Ugandan Diaspora. Archived from the original on 2 November 2020. Retrieved 15 July 2012. 
  10. "Beneath The Lies’ Nana Kaggwa Fit to Burst". Chimpreports. Archived from the original on 20 September 2016. Retrieved 15 May 2015. 
  11. "'Butterflies of Uganda' debuts at Greenway Court Theatre.". Backstage. NICOLE KRISTAL. http://www.backstage.com/news/butterflies-of-uganda-debuts-at-greenway-court-theatre/. Retrieved 4 September 2007. 
  12. http://www.backstage.com/review/la-theater/butterflies-of-uganda/
  13. https://web.archive.org/web/20170824135605/https://jump.ug/lifestyle-n-entertainment/nana-kagga-her-experience-in-the-ugandan-film-industry-jump-uganda
  14. "Don't Miss!! "Beneath the Lies" TV series, Created by Nana Kagga Macpherson, Premieres Dec 17th, Urban TV". Ugandan Diaspora News. Archived from the original on 2 November 2020. Retrieved 9 December 2015. 

Awon ona asopo ita

àtúnṣe