Nancy Charton
Nancy Charton Ph.D (tí wọ́n bí ní ọdún 1920, tó sì ṣaláìsí ní ọdún 2015) jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó máa jẹ oyè àlùfáà ní Anglican Church of Southern Africa.[1][2][3][4][5]
Nancy Charton | |
---|---|
Church | Anglican |
Province | Southern Africa |
Ordination | 1992 |
Personal details | |
Born | 1920 |
Died | November 11, 2015 Graaff Reinet | (ọmọ ọdún 94–95)
Charton jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ tó wá padà di ọ̀jọ̀gbọ́n ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣèlú ní Rhodes University. Yàtọ̀ sí èyí, ó tún jẹ́ díkínẹ́ẹ̀sì ní St Bartholomew's Church, Grahamstown. Ní oṣụ̀ kẹsàn-án ọdún 1992, David Russell yàn án gẹ́gẹ́ bí i àlùfáà ní Grahamstown Cathedral.
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣe- Charton, Nancy (2009). Meyer, Wilhelm Henry. ed. The Calling: The Story of a Pioneering Woman Priest. Pietermaritzburg: Cluster Publications. ISBN 978-1-875053-79-7. https://books.google.com/books?id=ZrhPAQAAIAAJ.
- Charton, Nancy (2007). "English‐speaking white elites in South African politics". Politikon 2 (2): 115–128. doi:10.1080/02589347508704682. ISSN 0258-9346.
- Charton, Nancy (1994). "The Witness of the Church of the Province of Southern Africa". International Review of Mission 83 (328): 153–157. doi:10.1111/j.1758-6631.1994.tb02355.x. ISSN 0020-8582.
- Brenda Nicholls; Nancy Charton; Mary Knowling (1998). The Diary of Robert John Mullins (1833-1913). Grahamstown: Rhodes University, Department of History. https://books.google.com/books?id=MfYvygAACAAJ.
- Charton, Nancy C J (1976). "Black elites in the Transkei". Politikon 3 (2): 61–74. doi:10.1080/02589347608704706. ISSN 0258-9346.
- Charton, Nancy (1980). Ciskei: Economics and Politics of Dependence in a South African Homeland. Croom Helm. ISBN 978-0-7099-0332-1. https://books.google.com/books?id=Ae0NAAAAQAAJ.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Meer 1998, p. 107.
- ↑ O'Meara & Greaves 1995, p. 36.
- ↑ Romero 1998, p. 83.
- ↑ McCoy 1994.
- ↑ Horowitz 1991, p. 75.