Nasir ol Molk Mosque
Nasir ol Molk Mosque (Persian: مسجد نصیر الملک – Masjed e Nasir ol Molk), tí wọ́n tún mọ̀ sí Mọ́ṣáláṣí Aláwọ̀ Pupa Fẹ́ẹ́rẹ́, jẹ́ mọ́ṣáláṣí ìbílẹ̀ ní Shiraz, Iran. Ó wà ní agbèègbè Gowad-e-Arabān nítòsí Šāh Čerāq Mosque. Mọ́ṣáláṣí yìí ní gílásì aláwọ̀ àràbarà tí ó sí ṣe àfihàn àwọn èròjà ìbílẹ̀ bíi Panj Kāse ("marún tí ó tẹ̀") . Wón máa ń sàbà pèé ní Mọ́ṣáláṣí Aláwọ̀ Pupa Fẹ́ẹ́rẹ́,[1] nítorí lílo áwọ̀ pupa fẹ́ẹ́rẹ́ sílẹ̀ fún ẹ̀ṣọ́ inú rẹ̀.[2]
Nasir ol Molk Mosque | |
---|---|
Inside view | |
Basic information | |
Location | Shiraz, Iran |
Province | Fars Province |
Municipality | Shiraz County |
Status | Active |
Architectural description | |
Architectural type | Mosque |
Architectural style | Iranian architecture |
Year completed | 1888 |
Ìtàn
àtúnṣeWọ́n kọ́ mọ́ṣáláṣí yìí nígbà àkókò Qajar, wọ́n sì ń lòó lábẹ́ ààbò Endowment Foundation of Nasir ol Molk. Wọ́n kọ́ọ láàrín Ọdún 1876 sí 1888 nípa àṣẹ Mirzā Hasan Ali (Nasir ol Molk) tí ó jẹ́ ọba Qajar.[3] Àwọn aṣàpẹẹrẹ ayàwòrán ni Mohammad Hasan-e-Memār, ayàwòrán ọmọ orílẹ̀ èdè Iran, àti Mohammad Rezā Kāshi-Sāz-e-Širāzi.[4]
Ìtọ́jú
àtúnṣeÀtúnṣe, ààbò, àti ìtọ́jú ohun ìṣẹ̀báyé yìí wà ní ìṣàkóso Endowment Foundation of Nasir ol Molk.
ibi ìṣàfihà fọ́tò
àtúnṣe-
Àbáwọlé
-
Àgbàlá mọ́ṣáláṣí yìí
-
Wíwò lati inú
-
Òkè àjà ẹ̀
-
gílásì aláwọ̀ àràbarà inú mọ́ṣáláṣí yìí
Tún wo
àtúnṣeMedia related to Nasirolmolk mosque ní Wikimedia Commons
- List of Mosques in Iran
- Architecture of Iran
Àjápọ̀ látìta
àtúnṣe- Nasir ol Molk Mosque on Art-Days.com Archived 2021-03-02 at the Wayback Machine.
- Nasir ol Molk Mosque on Albert-Videt.eu (French)
- BBC Persian: Nasir ol Molk (Persian)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Mosque of Whirling Colours: A Mixture of Architecture and Art in Nasīr al-Mulk Mosque in Shiraz, Iran Archived 2016-05-11 at the Wayback Machine., Cem Nizamoglu, MuslimHeritage.com
- ↑ CNN: Why your next vacation could be in Iran, Frederik Pleitgen – July 14, 2015
- ↑ Stunning Mosque In Iran Becomes A Magnificent Kaleidoscope When The Sun Rises, DeMilked Magazine
- ↑ Patricia L. Baker; Hilary Smith; Maria Oleynik (2014). Iran. Bradt Travel Guides. pp. 185–. ISBN 978-1-84162-402-0. http://books.google.com/books?id=RT0bAgAAQBAJ&pg=PA185.