Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Wọ́n bí Nasiru ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù kẹsàn-án ọdún 1977, [1] ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá Kaduna ní ìpínlẹ̀ Kaduna. Nasiru kẹ́kọ̀ọ́ gboyè PGD nínú ẹ̀kọ́-ìmọ̀ Mass Communication ní BUK, gboyè PGD nínú ẹ̀kọ́-ìmọ̀ Ìbáṣepọ̀ orílẹ̀-èdè àti Diplomacy ní àfikún sí ẹ̀kọ́ HND nínú ẹ̀kọ́-ìmọ̀ Mass Communication ní Kaduna Polytechnic, ní ìpínlẹ̀ Kaduna.[2]



Oníṣẹ́-ìròyìn

Nasiru bẹ̀rẹ̀ ìṣe ìròyìn gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ tí ó yàn láàyò ní ABG Group. Ó ṣiṣẹ́ fún ìgbà ráńpẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òǹkọ́ṣẹ́ lábẹ́ àmójútó pẹ̀lú KSMC ní ìlu Kaduna kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ oníwé-ìròyìn Daily Trust lákọ̀ọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ arakẹni ní oṣù mẹ́jọ 2000 kí ó tó wá di òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ gan ní ọdún 2004.[3][4] Ní Daily Trust, Ó jẹ́ aṣojú yàn ayẹ̀ròyìn wò (ní Sátidé) ní ọdún 2012, kí wọ́n tó dá a padà sí igbákejì ayẹ̀ròyìn wò Daily. Ní ọdún 2014 [5] kí wọ́n tó bòǹtẹ̀lú gẹ́gẹ́ bíi ayẹ̀ròyìn wò ní ọdún 2016.[6][7][8] Gẹ́gẹ́ bí ayẹ̀ròyìn wò, ó gba àmì-ẹ̀yẹ tí ayẹ̀ròyìn wò jùlọ tí ọdún náà ní ọdún 2016[9][10] tí ìwé-ìròyìn Daily sì gba àmì-ẹ̀yẹ ìwé-ìròyìn tí ọdún náà.[11][12]

Ní ọdún 2019, wọ́n yan Nasiru gẹ́gẹ́ bíi olùṣàkóso ayẹ̀ròyìn wò tí Daily Trust.[13][14] Ó fi iṣẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 2020 láti lọ dára pọ̀ mọ́ Dateline Nigeria gẹ́gẹ́ bíi Olú-ayẹ̀ròyìn wò.[15][16][17][18]

Ó máa ń kó ìròyìn fún Gamji.com láti ọdún 2015[19][20] [21] ó sì máa ń dá sí ti àwọn ilé-iṣẹ́ yòókù.[22]

[23][24] [25][26]

  1. "Nasiru Lawal - Editor in Chief at Dateline Nigeria". Apollo.io. Retrieved 2022-06-27. 
  2. "Kaduna train attack: Abductors release photos, families identify captives". BluePrint. Retrieved 2022-04-27. 
  3. "Fuel Crisis - Filling Stations Turn Black Market Outlets". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 May 2009. Retrieved 6 March 2022. 
  4. "Video Shows Ex-Commissioner's Execution, by Nasiru L. Abubakar". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 August 2009. Retrieved 6 July 2022. 
  5. "Nigeria: Daily Trust Appoints Acting Editor". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 November 2014. Retrieved 6 July 2022. 
  6. "Nasiru L. Abubakar is now the substantive Editor of Daily Trust". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 February 2016. Retrieved 6 July 2022. 
  7. "Celebration Of Kabiru Yusuf’s Election As NPAN". Tribune (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 May 2021. Retrieved 16 January 2022. 
  8. "Kaduna: FRCN Management Condoles Immediate Past NUJ Kaduna Chairman Over Demise Of Father". News Reservoir (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 April 2022. Retrieved 1 March 2022. 
  9. "Nigeria Newspaper Awards... And the Winner Is?". All Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 December 2016. Retrieved 6 June 2022. 
  10. "The Nation confirms class with harvest of 13 awards at NMMA". The Nation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 December 2016. Retrieved 21 December 2021. 
  11. "Daily Trust wins 2016 Newspaper of the year award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 13 July 2022. 
  12. "Winners of Nigeria Media Merit Award". Punch Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 6 June 2022. 
  13. "Media Trust appoints new Editor-in-Chief". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 30 December 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  14. "Media Trust staff eulogize outgoing managing, production editors". Press Reader (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 31 December 2021. 
  15. "Media Trust appoints new Editor-in-Chief". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2014. Retrieved 30 December 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  16. "Former Daily Trust editors join Dateline Nigeria". Daily Nigerian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1 December 2020. Retrieved 30 December 2020. 
  17. "Former Daily Trust editors join Dateline Nigeria - The Cable". The Cable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1 December 2020. Retrieved 30 December 2020. 
  18. "Nasiru L. Abubakar join Dateline Nigeria as Editor in Chief". PR Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 1 December 2020. Retrieved 30 December 2020. 
  19. "Letter to ‘President’ Jerry Gana, by Nasiru L. Abubakar". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 September 2015. Retrieved 9 June 2021. 
  20. "Bukar’s Legitimate Ignorance By Nasiru Lawal". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2016. 
  21. "Between Gumi and Nigerian Politicians, by Nasiru L. Abubakar" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 September 2007. Retrieved 6 February 2021. 
  22. "Imam Dahiru Lawal Abubakar: 1970-2022". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2022. 
  23. "Letter to ‘President’ Jerry Gana, by Nasiru L. Abubakar". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 September 2015. Retrieved 9 June 2021. 
  24. "Bukar’s Legitimate Ignorance By Nasiru Lawal". Gamji.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2016. 
  25. "Between Gumi and Nigerian Politicians, by Nasiru L. Abubakar" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 September 2007. Retrieved 6 February 2021. 
  26. "Imam Dahiru Lawal Abubakar: 1970-2022". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 July 2022.