Nassima Saifi
Nassima Saifi (ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹ́wá ọdún 1988) jẹ́ eléré ìdárayá àwọ́n tí kò lẹ́sẹ̀ láti orílẹ̀ èdè Algeria tí ó díjé ní ìpele júju irin F58. Ó maa ń sába ju irin ti ọlọ́nàn jínjìn àti ti kúkurú, Saifi ti gba àmì ẹ̀yẹ wúrà ti Paralympic lẹ́ẹ̀méjì àti àmì ẹ̀yẹ wúrà gbogbo àgbáyé lẹ́ẹ̀mẹ́ta
Ìgbésíayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí saifi ní ìlu Mila ní orílẹ̀ èdè Algeria ní ọdún 1988.[1] Wọ́n bíi pẹ̀lú ara pípé, ìṣẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ọkọ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1998 ni ó sọ ọ́ di alábọ̀ ara tí wọ́n fi gé ẹsẹ̀ rẹ̀ .[2] Bàbá rẹ̀ ṣe àkíyèsí wípé ó lè fẹ́ ṣeré ní ìgbà tí ọwọ́ rẹ̀ bá dilẹ̀, ó sí gbàá ní ìyànjú wípé kí ó mú eré ìdárayá gẹ́gẹ́ bi iṣẹ́ àṣelà. Ó darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ eré ìdárayá àwọn tí kò lẹ́sẹ́ ní Mila.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Saifi, Nassima". Paralympic.org. Retrieved 4 September 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Saifi, Nassima". IPC. Retrieved 4 September 2016.
- ↑ "Nassima Saifi, championne du monde du lancer de disque" (in French). DjaZairess. Retrieved 19 February 2017.