Natasha Akpoti
Agbẹjọ̀rò Ọmọ Nàíjírìa
(Àtúnjúwe láti Natasha Apkoti)
Natasha Akpoti jẹ́ Agbẹjọ̀ró àti Óṣélù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjírìa[1]. Natasha gbé àpotí fún Ilé-ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ ọmọ Social Democratic Party.
Natasha Akpoti | |
---|---|
Natasha Akpoti | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọmọorílẹ̀-èdè | ọmọ ìlú Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Social Democratic Party (SDP) |