National Museum tí orílè-èdè Nàìjíríà

Musiomu Orilẹ-ede Naijiria jẹ ile musiọmu ní ìpínlè Èkó, orílè-èdè Nàìjíríà Ile-išẹ musiọmu naa ni akojọpọ àwon ère ati aworan nlá ni Naijiria, pẹlu awọn awọn ohun-ọṣọ. [1] Musiomu náà wa ni Onikan, Lagos Island, Ipinle Eko. Ówà labé idari National Commission for Museums and Monuments.

Ọgbà níwájú Musíọ́mù orílẹ̀ èdè Nàìjíríà

Kenneth Murray dá Musiomu náà kalè ní odún 1957, a da Musiomu náà kalè láti jé ilé ipamo fún àwon ohun esó àti ohun àsà orílè-èdè Nàìjíríà.[2]

Àwon atojo òhun èsó

àtúnṣe

Musiomu náà jé ilé fún àwon ohun esó àti àsà bi egbèrún metadinlagota, [3] àwon ohun àsà bi ibon, aso egungun, ìlù àti ere.

Ibi Àwòrán

àtúnṣe

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. Nations Encyclopedia
  2. Board, Editorial (March 16, 2016). "Rehabilitating the National Museum - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved September 10, 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "The National Museum of Lagos Six Enthralling Masterworks at the National". RefinedNG. October 9, 2021. Retrieved September 10, 2022.