Ndidi Madu
Ndidi Madu (tí wọ́n bí ní March 17, 1989) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ tí wón bí sí ìlú America. Ó gbá bọ́ọ̀lù náà fún Broni àti Nigerian national team.[1]
No. 12 – Broni | ||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Position | Forward | |||||||||||||
League | Serie A1 | |||||||||||||
Personal information | ||||||||||||||
Born | 17 Oṣù Kẹta 1989 Nashville, United States | |||||||||||||
Nationality | American/Nigerian | |||||||||||||
Listed height | 6 ft 2 in (1.88 m) | |||||||||||||
Career information | ||||||||||||||
College | Florida | |||||||||||||
Medals
|
Àwọn ìṣirò ti Florida statistics
àtúnṣeOrísun[2]
GP | Games played | GS | Games started | MPG | Minutes per game |
FG% | Field goal percentage | 3P% | 3-point field goal percentage | FT% | Free throw percentage |
RPG | Rebounds per game | APG | Assists per game | SPG | Steals per game |
BPG | Blocks per game | PPG | Points per game | Bold | Career high |
Year | Team | GP | Points | FG% | 3P% | FT% | RPG | APG | SPG | BPG | PPG |
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
2007-08 | Florida | 1 | 3 | 50.0% | 0.0% | 50.0% | 3.0 | - | - | - | 3.0 |
2008-09 | Florida | 26 | 62 | 51.0% | 0.0% | 50.0% | 1.8 | 0.3 | 0.3 | 0.3 | 2.4 |
2009-10 | Florida | 32 | 121 | 35.0% | 0.0% | 59.5% | 2.9 | 0.5 | 0.5 | 0.3 | 3.8 |
2010-11 | Florida | 35 | 251 | 45.4% | 0.0% | 76.7% | 5.0 | 0.5 | 0.5 | 0.4 | 7.2 |
2011-12 | Florida | 33 | 165 | 39.7% | 28.0% | 61.5% | 4.3 | 1.2 | 0.6 | 0.3 | 5.0 |
Career | 127 | 481 | 41.9% | 28.0% | 62.5% | 3.6 | 0.6 | 0.5 | 0.3 | 3.8 |
Iṣẹ́ rẹ̀ ní ẹgbẹ́ àgbáyé
àtúnṣeÓ kópa nínú ìdíje ti 2017 Women's Afrobasket.[3] Ó sì ní pọ́ìntì 3.9 pts, 3.9 RBG àti 1.6 APG nínú ìdíje náà.[4]
Ìfẹ̀yìntì rẹ̀
àtúnṣeNí ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà, ọdún 2018, Madu ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìfẹ̀yìntì rè nínú gbígbá bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n lórí ìtàkùn ẹ̀rọ-ayélujára,[5] ṣíwájú ìdíje ti 2018 FIBA Women's World cup ní ìlú Spain. Ó sọ ọ́ di mímọ̀ pé fífẹ̀yìntì yìí á ran òun lọ́wọ́ láti dojú lé ayé òun àti ìfẹ́ òun láti jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́gbá fún ẹgbẹ́ tó gbé kalẹ̀, ìyẹ́n Team Madu Foundation, tó níṣe pẹ̀lú ìdàgbàsókè àwọn ọ̀dọ́.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ FIBA profile
- ↑ "NCAA Statistics". web1.ncaa.org. Retrieved 2021-06-03.
- ↑ "Ndidi MADU at the FIBA Women's Afrobasket 2017". FIBA.basketball.
- ↑ "Ndidi Madu profile, FIBA Africa Champions Cup for Women 2015". FIBA.COM. Retrieved 2021-06-04.
- ↑ "BasketballWithinBorders - Training the World, One Baller at a Time".
- ↑ "Madu calls it quits ahead of FIBA Women's Basketball World Cup". FIBA.basketball.