Nduka Otiono
Nduka Anthony Otiono jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n, òǹkọ̀wé, akéwì àti akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú Canada. Òun ni olùdarí, Institute of African Studies, Carleton University, ní Ottawa, Canada[1][2][3][4] àwọn iṣẹ́-ìwádìí rẹ̀ sì dá lórí àwọn ìtàn àdúgbò tí ò lajú káàkiri ilẹ̀ Afrika. Bí i ìtàn àtẹnudẹ́nu, ìwé ìròyìn, àwọn orin gbajúmọ̀, àti ètò afẹ́. [5][6]
Nduka Anthony Otiono | |
---|---|
Born | Kano, Nigeria |
Nationality | Nigerian, Canadian |
Alma mater |
|
Doctoral advisor | Heather Zwicker |
Known for | DisPlace: The Poetry of Nduka Otiono |
Influences | Chinua Achebe |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Edeme, Victoria (2022-08-23). "Nigerian-born scholar shortlisted for Canadian poetry award". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-16.
- ↑ "Dr. Nduka Otiono". carleton.ca (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-16.
- ↑ "Nigeria: As Winner of Carnegie African Diaspora Scholar Fellowship, Nduka Otiono, Joins Delsu".
- ↑ "The media cannot be captured". The Vanguard.
- ↑ " Nigeria's Nduka Otiono Wins Research Excellence Award at Canadian University – Independent Newspaper Nigeria". independent.ng. Retrieved 2023-05-16.
- ↑ "Otiono, Nigerian-Canadian, appointed director of African studies institute at Carleton University". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-17. Retrieved 2023-05-16.