Neon Adejo
Neon Adejo Yunisa, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Neon Adejo ( tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin lélógún oṣù kẹwàá) jẹ́ akọrin ihinrere ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olórin àti aṣáájú ìsìn tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí orin “Eze Ebube”. [1]
Igbesiaye
àtúnṣeA bí Neon Adejo ni ọjọ́ kẹrin lélógún Oṣù Kẹwàá ní ìkòyí, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Òun ni àkọ́bí nínú àwọn ọmọ mẹ́fà nínú ìdílé àwọn òbi rẹ̀. [2] Ó dàgbà sínú ẹ̀sìn Mùsùlùmí ṣùgbọ́n ó padà di ẹlẹ́ṣin kìrìsìtẹ́nì
Ní 2023 ó kẹ́kọ̀ọ́ gba ìmò oyè Báṣẹ́lọ̀ Degree ní HISTORY AND INTERNATIONAL RELATIONS Kogi State University, Nigeria
Iṣẹ orin
àtúnṣeỌmọ ọdún mẹ́tàlá ni Adejo bẹ̀rẹ̀ orin ṣùgbọ́n ọdún 2014 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní pẹrẹwu Ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin ákọ́kọ́ rẹ̀ tí akọ́lẹ̀ TELL THE WORLD ní ọdún 2020 tí ó ní àwọn orin mẹ́wàá.
lẹ́hìn ọdún kan , ní Oṣù Kẹta ọdún 2021, Adejo ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin kejì rẹ̀ àti EP àkọ́kọ́ tí akole Orin Ọpẹ́ tí ó ní àwọn orin márùn-ún pẹ̀lú Eze Ebube àti Breathe On Me inclusive. [3]
Aworan aworan
àtúnṣeÀwọn àwo -orin
àtúnṣeAkọle | Ọjọ Tu silẹ | Awọn alaye |
---|---|---|
Nkankan bikose ihinrere | Oṣu Kẹsan 2022 |
|
Awọn orin ti Ọpẹ (EP) | Oṣu Kẹta ọdun 2021 |
|
Sọ fun agbaye | Oṣu Kẹrin Ọjọ 2020 |
|
- Mu kuro (2018)
- Chinecherem (2019)
- Onyenemema (2020)
- Amin (2021)
- Eze Ebube (2021)
- Eze Ebube II (2022)
Odun | Eye | Ẹka | Abajade | Ref |
---|---|---|---|---|
Ọdun 2023 | Eye Achievers Kingdom | Gbàá | [4] | |
Awọn akọle | Gbàá | |||
GX Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "How Eze Ebube was birthed, by artiste Neon Adejo". https://thenationonlineng.net/how-eze-ebube-was-birthed-by-artiste-neon-adejo/.
- ↑ "Neon Adejo And The Birth Of Afroworship". https://independent.ng/neon-adejo-and-the-birth-of-afroworship/.
- ↑ Songs of Gratitude - EP by Neon Adejo
- ↑ "Neon Adejo, Mike Abdul, Naomi, Ariyo win at Kingdom Achievers Award". https://thenationonlineng.net/mike-abdul-naomi-ariyo-win-at-kingdom-achievers-award/.