Néstor Kirchner

(Àtúnjúwe láti Nestor Kirchner)

Néstor Carlos Kirchner (25 February 1950 – 27 October 2010) je oloselu ara Argentina, to di Aare orile-ede Argentina lati 25 Osu Karun 2003 titi de 10 Osu Kejila 2007. Teletele, ohun ni Gomina Igberiko Santa Cruz lati 10 Osu Kejila 1991.[1] Fun igba die o je Akowe Agba fun Isokan awon Omo Orile-ede Guusu Amerika (UNASUR).

Néstor Kirchner
54th aarẹ orile-èdè Argentina
In office
25 May 2003 – 10 December 2007
Vice PresidentDaniel Scioli
AsíwájúEduardo Duhalde
Arọ́pòCristina Fernández de Kirchner
Secretary General of the Union of South American Nations
In office
4 May 2010 – 27 October 2010
AsíwájúPosition created
Arọ́pòTBA
Deputy of Argentina
For Buenos Aires Province
In office
3 December 2009 – 27 October 2010
Gómìnà Santa Cruz
In office
10 December 1991 – 25 May 2003
Vice GovernorSergio Acevedo (1991–1999)
Héctor Icazuriaga (1999–2003)
AsíwájúRicardo del Val
Arọ́pòHéctor Icazuriaga
Mayor of Río Gallegos
In office
1987–1991
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1950-02-25)25 Oṣù Kejì 1950
Río Gallegos, Santa Cruz, Argentina
Aláìsí27 October 2010(2010-10-27) (ọmọ ọdún 60)
Santa Cruz, Argentina
Ọmọorílẹ̀-èdèArgentine
Ẹgbẹ́ olóṣèlúFront for Victory,
(Justicialist Party)
(Àwọn) olólùfẹ́Cristina Fernández de Kirchner
Àwọn ọmọMáximo Kirchner
Florencia Kirchner
Alma materNational University of La Plata
ProfessionAgbẹjọro
Signature

Ìgbésíayé re

àtúnṣe

Kirchner ní wọn bi ni ọdún 1950, ni Rio Gallegos, Santa Cruz. Bàbá rẹ, Néstor Carlos Kirchner pade Chilean María Juana Ostoic, wọn bí ọmọ mẹ́ta to orukọ wón n jẹ: Néstor, Alicia, ati María Cristina.[2] Nígbà ti o wa ni ilé-èkó gíga, ó ro pe ki o n di olùkọ́, àmọ́n aile pe àwọn ohun miran daada se ìdínà fún.[3][2]


  1. BBC News, Americas, Country profiles: Argentina. Leaders.
  2. 2.0 2.1 Alberto Amato (28 October 2010). "Un chico formado bajo los implacables vientos del sur" [A kid raised under the implacable winds of the south] (in Èdè Sípáníìṣì). Clarín. Retrieved 3 May 2016. 
  3. Majul 2009, p. 17.