New Money (TV series)
New Money (Owó tuntun) jẹ́ eré orí ẹ̀rọ mohùnmáwòrán ni ilu Amẹ́ríkà tí o bọ́ s'órí afẹ́fẹ́ ni ọjọ́ kọkan-din-lọgbọn oṣu karun ọdun 2015 l'órí ẹ̀rọ ayélujára mohùnmáwòrán E!.[1][2] Eré yi ti a pín sí abala mẹ́fà dá l'órí bí àwọn tí ó l'ọ́rọ̀ púpọ̀púpọ̀ ṣe ma n na owo wọn àti iru igbe ayé ti wọn ma n gbe. Ilé iṣẹ́ mohùnmáwòrán Leftfield ni o ṣe àgbékalẹ̀ ere naa.[3]
New Money | |
---|---|
Fáìlì:New Money E show logo.png | |
Genre | Reality |
Country of origin | United States |
Original language(s) | English |
No. of seasons | 1 |
No. of episodes | 6 |
Production | |
Executive producer(s) |
|
Camera setup | Multiple |
Running time | 30 minutes |
Production company(s) |
|
Release | |
Original network | E! |
Picture format | 480i (SDTV) 1080i (HDTV) |
Original release | Oṣù Kàrún 29, 2015 | – Oṣù Kẹfà 26, 2015
External links | |
Website |
Eré yi bọ s'órí afẹ́fẹ́ ni ilu Amẹ́ríkà ní ọjọ́ kọkan-din-lọgbon oṣù karun ọdún 2015 sí ojú iworan àwọn ènìyàn tí o tó okoo lé ní'gba o le ẹyọ kan. Ni àkọ́kọ́ ti ere yi bo sori afẹ́fẹ́, eniyan ti o to ẹgbẹ̀rún lọ́nà mẹta-le-legbesan ni o ja kuro lójú ìwòran eré yii ti a pe ni lead-in The Soup. Ni ilu Australia, ere yi bọ sori afẹ́fẹ́ ni ọjọ kẹta oṣu kẹfa ọdun 2015 lórí èka E! ni ilu Australia.[4]