Eya Ngbaka tabi M'Baka je eya eniyan ni Orile-ede Olominira Arin ile Afrika.

Ngbaka

Awọn wọnyi jẹ awon to ń gbé ìlú Ngbaka, kò sì sí agbára kan to da wọn pọ, ńṣe ni olukuluku n se bi o ti fẹ láàrin ìlú. Awọn ẹya náà ń gbe Ubangi.