Ngozi Okobi

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Ngozi Okobi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 14, óṣu December ni ọdun 1993. Arabinrin naa ṣere fun Swedish club Eskilstuna United DFF gẹgẹbi ipo forward[1][2][3].

Ngozi Okobi-Okeoghene
Personal information
OrúkọNgozi Sonia Okobi-Okeoghene
Ọjọ́ ìbí14 Oṣù Kejìlá 1993 (1993-12-14) (ọmọ ọdún 31)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.65m
Playing positionForward
Club information
Current clubEskilstuna United DFF
Number25
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2010–2015Delta Queens
2015Washington Spirit4(0)
2016–2017Vittsjö GIK38(3)
2018–Eskilstuna United DFF68(6)
National team
2010–Nigeria women's national football team27(4)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 30 August 2020.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 17 June 2015

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Ngozi kopa ninu FIFA U-17 Cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 2008, 2010 ati FIFA U-20 Cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 2012 nibi ti o jẹ àṣoju team awọn obinrin apapọ ilẹ naigiria lori bọọlu[4].
  • Ngozi kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2010, 2012 ati 2014[5].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://us.soccerway.com/players/ngozi-okobi/150697/
  2. https://www.eurosport.com/football/ngozi-okobi_prs326806/person.shtml
  3. https://globalsportsarchive.com/people/soccer/ngozi-okobi/157050/
  4. https://www.fifa.com/tournaments/womens/u17womensworldcup/trinidadandtobago2010/teams/1915218
  5. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=287671&edicao_id=105111