Ngozi Opara (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣụ̀ kọkànlá ọdún 1971) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó máa ń kópa nínú ìdíje bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá. Ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin ní 1992 Summer Olympics.[1][2]

Ngozi Opara
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kọkànlá 1971 (1971-11-11) (ọmọ ọdún 53)
Sport
Erẹ́ìdárayáHandball

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Olympedia – Ngozi Opara". Olympedia – Main Page. 1971-11-11. Retrieved 2024-04-25. 
  2. "Ngozi OPARA". Olympics.com. 2023-06-12. Retrieved 2024-04-25.