Nichole Banna tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Virgin Mary jẹ́ òṣèrébìnrin àti aṣagbátẹrù fíìmù, tó ti ní ìfarahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò. Òun ló ṣagbátẹrù fíìmù Icheke Oku, èyí tó jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Igbo.[1][2]

Nichole Banna
Ọjọ́ìbíImo State, Nigeria
Orúkọ mírànVirgin Mary
Iléẹ̀kọ́ gígaRiver State University of Science and Technology
Iṣẹ́Film actress, producer

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ní ìbámu pẹ̀lú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tó ní pẹ̀lú ìwé-ìròyìn Punch àti Sunnews, òṣèrébìnrin yìí tó wá láti Ipinle Imo lọ sí ilé-ìwé Oliver heights ní Portharcourt fún ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ rẹ̀, àti ilé-ìwé Emmy Norberton fún ètò ẹ̀kọ́ girama. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè B.Sc. nínú ìmọ̀ computer science ní River State University of science and Technology.

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Ó ti kópa nínú fíìmù àgbéléwò oríṣiríṣi, bẹ́ẹ̀ sì ni ó ti ṣagbátẹrù fíìmù kan, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Icheke Oku.[3]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jù ní ayẹyẹ BON award, ní ọdún 2016.[8]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. sunnews (2017-04-09). "Why they call me Virgin Mary – Nichole Banna, actress". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-04. 
  2. "My guardians opposed my acting career — Nichole Banna". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-26. Retrieved 2022-08-04. 
  3. izuzu, chibumga (2016-07-22). "Watch Blossom Chukwujekwu, Nichole Banna, Daniel K Daniel in Igbo movie". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-04. 
  4. "Lilian Afeghai debut movie, bound, hits the cinemas". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-17. Archived from the original on 2021-10-04. Retrieved 2022-08-04. 
  5. "Lilian Afegbai makes production debut with ‘Bound’". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-11. Retrieved 2022-08-04. 
  6. "Matilda Lambert, Majid Michel go for broke in ‘Deepest Cut’". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-01. Retrieved 2022-08-04. 
  7. "Lizzygold Onuwaje’s second movie, ‘Just a night’, pitches Majid Michel against Femi Jacobs". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-07-15. Retrieved 2022-08-04. 
  8. Augoye, Jayne (2016-12-14). "Alexx Ekubo, Yomi Fabiyi, Toyin Aihmakhu, others bag BON Awards". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-04.