Nicolás Avellaneda
Nicolás Remigio Aurelio Avellaneda Silva (3 October 1837 – 24 November 1885) jẹ́ ará orílè-èdèArgentine olóṣèlú ati oniróyìn, Aarẹ orile-èdè Argentina larin 1874 sí 1880.
Nicolás Avellaneda | |
---|---|
National Senator | |
In office May 3, 1882 – November 25, 1885 | |
Constituency | Tucumán |
In office May 3, 1884 – October 10, 1884 | |
Constituency | Tucumán |
Ààrẹ orile-èdè Argentina | |
In office October 12, 1874 – October 11, 1880 | |
Vice President | Mariano Acosta |
Asíwájú | Domingo F. Sarmiento |
Arọ́pò | Julio A. Roca |
Minister of Justice and Public Instruction | |
In office October 12, 1868 – August 10, 1873 | |
Ààrẹ | Domingo Faustino Sarmiento |
Asíwájú | Eduardo Costa |
Arọ́pò | Juan Crisóstomo Albarracín |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | October 3, 1837[1] San Miguel de Tucumán, Tucumán |
Aláìsí | November 24, 1885 At sea | (ọmọ ọdún 48)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentina |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Autonomist Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Carmen Nóbrega Miguens[2] |
Profession | Agbẹjọro |
Biography
àtúnṣeWọn bi Nicolás si San Miguel de Tucumán, ìyá rẹ̀ ko lọ Bolivia pẹ̀lú rẹ̀ leyin ìkú bàbá rẹ̀, Marco Avellaneda. O ka nipa ìgbẹ́jọ́rò ni Córdoba, ti o si parí ekó náà. Padà ṣí Tucumán o da El Eco del Norte sí lẹ̀, tí sì ko lọ si Buenos Aires ni ọdún 1857,ti o si di oludari El Nacional ati alatunkọ ni El Comercio de la Plata. O pari ẹ̀kọ́ re ni Buenos Aires, níbi ti o ti pade Domingo Faustino Sarmiento. Sarmiento ran lọwọ lati jẹ olùkọ́ ní University of Buenos Aires.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "F. Pigna". Archived from the original on 2013-12-15. Retrieved 2010-09-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ NICOLÁS AVELLANEDA (1874 – 1880) | Casa Rosada