Nigerian Bar Association
Ẹgbẹ́ Nigerian Bar Association (NBA) jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn adajọ́ tí wọ́n ní ìwé-àṣẹ lọ́rílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ẹgbẹ́ tí wọ́n máa ń jà fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn, ẹ̀tọ́ ìlànà òfin àti Ìjọba tó dára lórílẹ̀-èdè Nigeria.[1]
Nigerian Bar Association | |
---|---|
Nigerian Bar Association | |
Motto | Promoting the Rule of Law |
Type | Professional Association |
Purpose/focus | Promote legal professionalism |
Ibùdó | Abuja |
Official languages | English |
President | Olumide Akpata |
General Secretary | Joyce Oduah |
Website | nigerianbar.org.ng |
Ọ̀gbẹ́ni Olumide Akpata ni Ààrẹ ẹgbẹ́ náà lọ́wọ́lọ́wọ́.[2] and the current General Secretary is Joyce Oduah.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Nigerian Bar Association". Namati (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-26.
- ↑ "Akpata, an Underdog, is New NBA President". This Day. This Day Newspaper. August 2, 2020. Retrieved August 9, 2020.
- ↑ ahuchaoguizu (2020-08-08). "NBA General Secretary Elect Joyce Oduah(FICMC), Visits NBA First Female General Secretary". Nigeria News Today | True Tells Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-01-15. Retrieved 2020-09-02.