Nike Folayan
Dr Nike Folayan MBE tí a bí ní ọdún 1978 jẹ́ Chartered Engineer àti Telecommunications Engineering Consultant. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ àti alága fún Association for Black and Minority Ethnic Engineers[1] tí ó ń kéde ethnic diversity nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ ní UK.
Nike Folayan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1978 |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Kent University of Sheffield |
Employer | Parsons Brinckerhoff |
Gbajúmọ̀ fún | Association for Black and Minority Ethnic Engineers (AFBE-UK) |
Ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeFolayan gboyè MEng nínú electronic engineering ní University of Kent, ó sì gboyè PhD nínú antenna design ní University of Sheffield.[2]
Lẹ́yìn tó gboyè PhD, ó dara pọ̀ mọ́ Mott MacDonald gẹ́gẹ́ bíi Communications Engineer.[3] Ibí ni ó ti ṣiṣẹ́ lórí radio design lóríṣiríṣi àti àwọn communications systems bíi CCTV àti àwọn ẹ̀rọ agbóhùn sáfẹ́fẹ́.[4] Ó dara pọ̀ mọ́ Parsons Brinckerhoff ní ọdún 2013 níbi tí ó ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Systems Integration Consultant.[4] Ó ṣiṣẹ́ lórí àwọn infrastructure projects bíi CrossRail àti ṣíṣàtúnṣe Victoria Station.[5] Ní ọdún 2016, wọ́n gbe lọ ipò Associate Director fún Communications and Control láàárín Railways Division of WSP.[6]
Ìkéde fún Ìtànkálẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 2008, Folayan gba àmì-ẹ̀yẹ "Inspiring Leader within the Workplace".[7][8][9] Ní ọdún 2012, wọ́n ṣàfihàn Dr Folayan nínú Powerlist: Britain’s 100 most influential people of African and Caribbean heritage.[10] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùgbàlejò tí ó sọ̀rọ̀ ní Higher Education Academy STEM annual conference lọ́dún 2014.[11] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn trustee ní Engineering Development Trust àti ọmọ ẹgbẹ́ Science Council àti ẹgbẹ́ Transport for London.[12][13][14] Ó lọ́wọ́ sí ìtànkálẹ̀ Royal Academy of Engineer's. Ní ọdún 2017, Folayan sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ Institution of Engineering and Technology's "9 % is Not Enough".[15]
The Association for Black and Minority Ethnic Engineers
àtúnṣeNike Folayan àti àbúrò rẹ̀ Ollie Folayan ló ṣe ìdásílẹ̀ Association for Black and Minority Ethnic Engineers (AFBE-UK) lọ́dún 2007, wọ́n sì jẹ́ alága ìgbìmọ̀ náà.[16] Lọ́dún 2011, Vince Cable tí ó jẹ́ akọ̀wé fún State for Business, Innovation and Skills nígbà náà fara hàn ní AFBE-UK’s seminar lórí infrastructure ní UK.[17][18] Ní ọdún 2016, ó darí ètò kan tó rí sí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ láti yunifásítì lóríṣiríṣi ní ìlú London láti kópa nínú àwọn iṣẹ́ lóríṣiríṣi tí ó le ràn wọ́n lọ́wọ́.[19][20]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Home - Association For BME Engineers (AFBE-UK)". afbe.org.uk. Retrieved 2020-01-24.
- ↑ "A sense of belonging in engineering - Create the Future" (in en-US). Create the Future. 2017-06-09. Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121072127/http://qeprize.org/createthefuture/sense-belonging-engineering/.
- ↑ "Young, gifted and black" (in en). Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121125752/http://www.voice-online.co.uk/article/young-gifted-and-black?quicktabs_nodesblock=2.
- ↑ 4.0 4.1 "People integration systems - The IET". www.theiet.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 21 January 2018. Retrieved 2018-01-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Female engineers: The women solving real-world problems" (in en-GB). The Independent. 2015-10-19. https://www.independent.co.uk/extras/jobs/female-engineers-the-women-solving-real-world-problems-a6699661.html.
- ↑ "A fascination for TVs inspired me to be an engineer: Nike Folayan - Melan Mag" (in en-GB). Melan Mag. 2017-10-27. http://melanmag.com/2017/10/27/a-fascination-for-tvs-inspired-me-to-be-an-engineer-nike-folayan/.
- ↑ "Enterprising women shine at Precious Awards - Ethnic Now". www.ethnicnow.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 21 January 2018. Retrieved 2018-01-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Precious Awards 2008". preciousawards.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 21 January 2018. Retrieved 2018-01-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ preciousonline (2008-12-02), Precious Awards 2008 | Nike Folayan | Mott Macdonald UK | Winner :: Inspiring Leader within the Workplace, retrieved 2018-01-20
- ↑ "About Us - Association For BME Engineers (AFBE-UK)". afbe.org.uk. Archived from the original on 2019-11-02. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ "STEM Careers for All? Diversity In Engineering | Higher Education Academy". www.heacademy.ac.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ "4 volunteers we want to thank - The Science Council" (in en-GB). The Science Council. 2016-04-20. http://sciencecouncil.org/4-volunteers-we-want-to-thank/.
- ↑ "Trustees | etrust". www.etrust.org.uk (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ "Association Established To Give Black and Minority Ethnic People Access to Opportunities in STEM Celebrates 10th Anniversary in London" (in en-GB). Ariatu Public Relations. Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121125734/http://www.ariatupublicrelations.com/news/afbeanniversarygala.
- ↑ "#9PercentIsNotEnough Conference - IET Events". events.theiet.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ "About Us - Association For BME Engineers (AFBE-UK)". afbe.org.uk. Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ "AFBE-UK Scotland | AFBE-UK Scotland". www.afbescotland.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-01-21. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ "Vince Cable to speak on Engineering Infrastructure in the UK". PRLog. Retrieved 2018-01-20.
- ↑ AFBE UK (2016-08-01), AFBE-UK's Transition in London, retrieved 2018-01-20
- ↑ Tideway. "Transition - Tideway helps redress the balance of our industry workforce - Tideway | Reconnecting London with the River Thames" (in en). Tideway. Archived from the original on 2018-01-21. https://web.archive.org/web/20180121184238/https://www.tideway.london/news/media-centre/transition-tideway-helps-redress-the-balance-of-our-industry-workforce/.