Yolande Cornelia "Nikki" Giovanni, Jr.[1][2] (ibi June 7, 1943 o si ku ni Oṣu kejila ọjọ 10, ọdun 2024) je ako-ewi, olukowe, alawiso, alakitiyan, ati oluko ara Amerika. Ikan ninu awon akoewi to gbajumojulo lagbaye,[2] ninu awon ise re ni awon iwe ewi, awo-orin ewi, ati awon ayoka orisirisi ti won da lori eya, oro awujo ati iwe omode. O ti gba opolopo ebun, ninu won ni Ebun Eso Langston Hughes, Ebun Eniyan NAACP. Won ti yan fun Ebun Grammy, fun awo-orin re The Nikki Giovanni Poetry Collection.[2]

Nikki Giovanni
Nikki Giovanni un soro ni Yunifasiti Emory, 2008
Ọjọ́ ìbí7 Oṣù Kẹfà 1943 (1943-06-07) (ọmọ ọdún 81)
Knoxville, Tennessee
Iṣẹ́Olukowe, ako-ewi, alakitiyan, olukowe
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerika
Ìgbà1960s–2024
Website
nikki-giovanni.com


\

  1. "Nikki Giovanni", Biography.com.
  2. 2.0 2.1 2.2 Jane M. Barstow, Yolanda Williams Page (eds), "Nikki Giovanni", Encyclopedia of African American Women Writers (Greenwood Publishing Group, 2007), p. 213.