Nina Norshie jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 14, óṣu september ni ọdun 2001. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Berry gẹgẹ̀bi defender.

Àṣeyọri àtúnṣe

  • Nina kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2016 ati 2018.

Itọkasi àtúnṣe