Nkechi Mbilitam
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Nkechi Mbilitam jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15, óṣu April ni ọdun 1974. Arabinrin naa ṣere fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria lori bọọlu[1][2][3]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kẹrin 1974 | ||
Playing position | Midfielder | ||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 5 June 1995 (before the 1995 FIFA Women's World Cup) |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Nkechi wa lara awọn agbabọọlu to kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 1991 ati 1995[4][5].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.eurosport.com/football/nkechi-mbilitam_prs414597/person.shtml
- ↑ https://fbref.com/en/players/dfef6715/Nkechi-Mbilitam
- ↑ https://ng.soccerway.com/players/nkechi-mbilitam/291470/
- ↑ https://www.soccerpunter.com/players/291470-Nkechi-Mbilitam
- ↑ https://www.fifa.com/en/tournaments/womens/womensworldcup/chinapr1991/match-center/21985