Nkem Akaraiwe
Nkem Akaraiwe tí a bí ní Ọjọ́ kejìlélógún osù kejìlá Ọdún 1996 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Nàìjíríà fún First Bank àti ẹgbẹ́ Nàìjíríà .[1][2]
No. 12 – First Bank | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Position | Iwájú | ||||||
League | ZWBL | ||||||
Personal information | |||||||
Born | Ọjọ́ kejìlélógún osù kejìlá Ọdún 1996 Okwe, Nigeria | ||||||
Nationality | Nàìjíríà | ||||||
Listed height | 6 ft 0 in (1.83 m) | ||||||
Listed weight | 154 lb (70 kg) | ||||||
Career information | |||||||
NBA draft | 2018 / Undrafted | ||||||
Medals
|
Ó kópa nínú ife àgbáyé eré bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá ti àwọn obìrin ti ọdún 2018 (2018 FIBA Women's Basketball World Cup).[3]