Ẹ̀bùn Nobel nínú Ìṣiṣẹ́ògùn

(Àtúnjúwe láti Nobel Prize for Chemistry)

Ẹ̀bùn Nobel fún Kẹ́místrì (Nobelpriset i kemi) je ebun ododun ti ti Akademy Alade ile Sweden fun àwon Sayensi n se fun awon onimosayensi ninu orisirisi papa kẹ́místrì. O je ikan ninu awon Ẹ̀bùn Nobel marun ti ogún Alfred Nobel se sile ni odun 1895.

Àwòrán Nobel prize nínú Ìṣòògùn.
Ẹ̀bùn Nobel nínú Kẹ́místrì
The Nobel Prize in Chemistry
Bíbún fún Outstanding contributions in Chemistry
Látọwọ́ Royal Swedish Academy of Sciences
Orílẹ̀-èdè Sweden
Bíbún láàkọ́kọ́ 1901
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ http://nobelprize.org