Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn
(Àtúnjúwe láti Nobel Prize for Physiology or Medicine)
Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn (Àdàkọ:Lang-sv) latowo Nobel Foundation, je ebun odoodun fun ipa pataki ninu ise iwosan. O je ikan larin awon ebun Nobel marun ti Alfred Nobel dasile ni 1895 sinu ogun re, awon yioku je fun ipa pataki ninu Fisiksi, Kemistri, Litireso ati Alafia.
Ẹ̀bùn Nobel fún Ìwòsàn Nobel Prize in Physiology or Medicine | |
---|---|
Bíbún fún | Ipa pàtàkì nínú Ìwòsàn |
Látọwọ́ | Royal Swedish Academy of Sciences |
Orílẹ̀-èdè | Sweden |
Bíbún láàkọ́kọ́ | 1901 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | http://nobelprize.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |