Ẹ̀bùn Nobel nínú Ìṣiṣẹ́ògùn
(Àtúnjúwe láti Nobel fún Kẹ́místrì)
Ẹ̀bùn Nobel fún Kẹ́místrì (Nobelpriset i kemi) je ebun ododun ti ti Akademy Alade ile Sweden fun àwon Sayensi n se fun awon onimosayensi ninu orisirisi papa kẹ́místrì. O je ikan ninu awon Ẹ̀bùn Nobel marun ti ogún Alfred Nobel se sile ni odun 1895.
Ẹ̀bùn Nobel nínú Kẹ́místrì The Nobel Prize in Chemistry | |
---|---|
Bíbún fún | Outstanding contributions in Chemistry |
Látọwọ́ | Royal Swedish Academy of Sciences |
Orílẹ̀-èdè | Sweden |
Bíbún láàkọ́kọ́ | 1901 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | http://nobelprize.org |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |