Noor Alam Khalil Amini
Noor Alam Khalil Amini (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1952, tí ó sìn ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 2021) onímọ̀ àgbà Mùsùlùmí, ọ̀mọ̀wẹ́ àti oǹkọ̀wé èdè Arabic àti Urdu ọmọ Indian.[1] Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àgbà èdè Lárúbáwá àti lítíréṣọ̀ ní Darul Uloom Deoband[2]. Ìwénrẹ̀ Falastin Fi Intezari Salahidin jẹ́ àkànṣe lámèyítọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè àwọn ọ̀mọ̀wẹ́ ní Assam University, bákan náà, ìwé rẹ̀, Miftahul Arabia wà lára àwọn ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ dars-e-nizami ní madrasas.
Amini jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́-àná Darul Uloom Mau, Darul Uloom Deoband, Madrasa Aminia àti King Saud University. Lára àwọn ìwé rẹ̀ ni Wo Koh Kan Ki Baat, Harf-e-Shireen, Miftah al-Arabiyyah àti Falastin Fi Intezari Salahidin.
Ìgbèsi Àye Noor Alam Khalil Amini
àtúnṣeAmini kọ litireso larubawa ni Darul Uloom Nadwatul Ulama fun ọdun mẹwa lati ọdun 1972 de 1982. Lẹyin naa lo ṣiṣè ólukọ ni Darul Uloom Deoband fun ọkan dinlógóji ọdun. Noor jẹ olori olootu fun Iroyin óṣóóṣu Darul Uloom Deoband ti èdè larubawa Al-Dai[3]. A fun ni iwe ẹri idanilọla ti ààrẹ ni ọdun 2017[4]. Awọn ọmọ ààkẹẹkọ rẹ ju ẹgbẹẹrun lọ, lara wọn sini Mohammad Najeeb Qasmi.
Awọn ìṣẹ rẹ
àtúnṣe- Al-dawatul islamiyyah bayn al-ams wa al-yawm
Al-sahabatu wa makanatuhum fi al-Islam
- al-Muslimoona fi al-Hind
- Falastin Fi Intezari Salahidin
- Harf-e-Shireen
- Kya Islam Paspa Horaha hai
- Maujuda Saleebi Saihuni Jang
- Miftahul Arabia
- Mujtama'tuna al-ma'asarah wa al-tareequ ila al-Islam
- Mata Takoon ul Kitabaat-o- Muassirah?
Pas-e-Marg-e-Zindah
- Ta'allamu Al-arabiya Fa'innaha Min Deenikum
- Wo Koh Kan Ki Baat[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "مولانا نور عالم خلیل امینی عربی و اردو کی مشترکہ لسانی روایت کے علم بردار تھے:ابرار احمد اجراوی". Qindeel Online. 3 May 2021. https://qindeelonline.com/maulana-noor-alam-khaleel-ameeni-arabi-wa-urdu-ki-mushtarka-lisani-riwayat-ke-alam-bardar-the/.
- ↑ Nayab Hasan Qasmi. "Mawlāna Nūr Alam Khalīl Amīni" (in ur). Darul Uloom Deoband Ka Sahafati Manzarnama (2013 ed.). Deoband: Idara Tahqeeq-e-Islami. pp. 247–252.
- ↑ "Maulana Noor Alam Khalil Amini nominated for President's Award". The Siasat Daily. https://archive.siasat.com/news/maulana-noor-alam-khalil-amini-nominated-presidents-award-1394392/amp/.
- ↑ President Awards the Certificate of Honour 2017, HRD Ministry, GoI, retrieved 24 May 2020
- ↑ Mahtab, Ahsan, ed (16–31 January 2017). "Urdu Ke Farogh Mai Ulama-e-Deoband Ka 150 Saala Kirdar" (in ur). Fikr-e-Inqelab (All India Tanzeem Ulma-e-Haque Trust) 5 (112): 535.