Noureddine Aman Hassan
Noureddine Aman Hassan (ti a bi ni ọjọ keje oṣu karun, ọdun 1943) jẹ afẹṣẹja kan ti o dije ni kariaye fun Egypt .
Hassan ṣe aṣoju Chad ni 1972 Summer Olympics ni Munich ni Light-heavyweight kilasi, ni ipele akoko ti o doju ko ara orilẹ-ede Yugoslavia Mate Parlov, won da duro ni ipele keji, Mate Parlov si tẹsiwaju lati gba ami-ẹri goolu. [1]