Noureddine Bouyahyaoui
Noureddine Bouyahiaoui (Ni èdè larubawa: نور الدين البويحياوي) ni a bini ọjọ keje, óṣu January, ọdun 1955 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba to ṣèrè gẹgẹbi defender fun órilẹ ede Morocco[1][2][3][4].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kínní 1955 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Morocco | ||
Playing position | Defender (association football) | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
KAC Kenitra | |||
National team | |||
Morocco national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣèyọri
àtúnṣeElere naa ṣèrè fun KAC Kenitra. Ni ọdun 1986, Noureddine kopa ninu Cup Agbaye ti FIFA[5][6].