Nthathi Moshesh(bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1969) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà. Wọn yàn kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Award for Best Actress in a Supporting Role ni ọdún 2016

Nthati Moshesh
Moshesh in 2018
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹjọ 1969 (1969-08-28) (ọmọ ọdún 55)
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
Ẹ̀kọ́St. Andrew's School for Girls
Technikon Natal
Iṣẹ́Actress
Gbajúmọ̀ fúnScandal

Iṣẹ́

àtúnṣe

Nthathi tí kópa nínú àwọn eré bíi Soldier Soldier, Home Affairs àti Human Cargo.[1] Ní ọdún 2014, ó darapọ̀ mọ́ àwọn òṣèré fún èrè Saint and Sinners Soap[2]. Ní ọdún 2015 ó kópa nínú eré Ayanda tí wọn sì ṣe ìfihàn rẹ ayẹyẹ Durban International Film Festival[3]. Ipa rẹ̀ nínú eré yí lọ fàá tí wọ́n fi yàán kalẹ̀ fún àmì ẹ̀yẹ tí òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọdo Africa Movie Academy Award[4]. Ní ọdún 2016, ó gbà àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ South African Film and Television Awards[5]. Leyin ikú òṣèré Mary Makgatho, Nthathi sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ ribiti tí òṣèré na ṣe kí ó tó kú.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "It’s not about you, but what you represent' - Nthati Moshesh". ENCA. August 16, 2013. Archived from the original on 2014-06-26. Retrieved 2017-11-12. 
  2. BULELWA, DAYIMANI (August 7, 2014). "My acting career’s been revived". destinyconnect.com. Archived from the original on 2018-03-27. Retrieved 2017-11-12. 
  3. "Movie starring OC Ukeje to open Durban Film Festival". Pulse. June 8, 2015. Retrieved 2017-11-12. 
  4. "AMAA 2016: Adesua Etomi, OC Ukeje set to make history again". Vanguard. Retrieved 2017-11-12. 
  5. "Local film and TV stars celebrated at Saftas". Citizen. March 20, 2016. Retrieved 2017-11-12. 
  6. "Nthati Moshesh pays tribute to Mary Makgatho". Channel 24. Retrieved 2017-11-12.