Nzhelele Dam
Àdàkọ:Infobox dam Nzhelele Dam (Èyítí tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ tó ń jẹ́ Njelele Dam) jẹ́ irú arch type dam tí ó wà lórí Nzhelele River ní Limpopo Province, South Africa. Ó ní agbára ti 55.3 million m3.[1] Wọ́n ṣẹ̀dá ẹ̀ ni ọdún 1948.[2] Iṣẹ́ kókó pàtàkì tí dam ṣe ni láti jẹ́kí àwọn eweko dàgbàsókè ni ìrọ̀rùn àti ewu rẹ ti lọ sókè (3).
Àwọn Ìtọ́kasí