Oṣù Nínú Ọdún
Oṣù nínú ọdún ni àwọn oṣù tí a ní nínú ọdún kan. Oṣù méjìlá ni ń ṣe ọdún kan nínú àṣà Yorùbá gẹ́gẹ́ bíi tí àwọn òyìnbó.[1] Òṣùpá ni àwọn bàbà ńlá ń lò láti mọ ìgbà tí oṣù bá béèrè. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni iye ọjọ́ to máa ń ṣe oṣù kan kan kìí ju ọjọ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n lọ. Ìgbà mìíràn, àwọn ọjọ́ wọ̀nyí lè lé ọjọ́ kan tàbì mèjì sì ara wọn.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "12 Months of the Year (2024)". EnglishCentral Blog. 2023-08-14. Retrieved 2024-07-19.
- ↑ Ẹ̀kọ́ èdẹ̀ Yorùbá òde-òní - Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè Yorùbá Nàìjíríà