Obìnrin jẹ́ abo ènìyàn ti o ti balaga, ti o si je idakeji Ọkunrin. Saaju ki obinrin to balaga, won ma n pe obinrin omidan. Won ma n lo akojopo oro yi 'awon obinrin' gege bi ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin lai wo ti ọjọ orí

Àwọn obìnrin
Woman




Ami fun obinrin