Oba Otudeko
Oba Otudeko CFR tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹjọ ọdún 1943 jẹ́ oníṣòwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti alága Honeywell Group.[1][2] Ó fìgbà kan jé alága FBN Holdings àti olùdásílẹ̀ Oba Otudeko Foundation.[3][4][5][6]
Omoba Oba Otudeko CFR | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oba Otudeko 18 Oṣù Kẹjọ 1943 Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Olivet Baptist High School Leeds College of Commerce Harvard University Hult International Business School |
Iṣẹ́ | Entrepreneur, Founder and Chairman of Honeywell Group |
Ìgbà iṣẹ́ | 1972—present |
Gbajúmọ̀ fún | Entrepreneurship, Corporate Governance, Philanthropy |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeAyoola Oba Otudeko jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ibadan, ní ipinle Oyo, ní 18 August 1943 sínú ìdílé ọlọ́lá, èyí sì mu kí ó jẹ́ ọmọọba ní ilẹ̀ Yorùbá.[7] Ìyá rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò.[8] Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní St. John’s School, ní Oke-Agbo,[9] ní Ijebu-Igbo, ní ipinle Ogun, kí ó ṣẹ̀ tó lọ Olivet Baptist High School, ní Oyo.[8] Lẹ́yìn náà, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Accountancy ní Leeds College of Commerce Leeds, Yorkshire, United Kingdom (èyí tó ti wá wà lára Leeds Beckett University).[10] Oba Otudeko jẹ́ Chartered Banker, Chartered Accountant àti Chartered Corporate Secretary.[11]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Oba Otudeko". www.forbes.com. Retrieved June 4, 2017.
- ↑ "Oba Otudeko" (in en). Forbes. https://www.forbes.com/profile/oba-otudeko/.
- ↑ "Otudeko, FBN Holdings Group Chairman leads Conversation at the Africa CEO Forum 2017". www.proshareng.com. March 21, 2017.
- ↑ "Founder: Dr. Oba Otudeko". obaotudekofoundation.org.
- ↑ Agekameh, Dele (30 March 2016). "Oba Otudeko: Celebrating an Icon". The Nation newspaper. http://thenationonlineng.net/oba-otudeko-celebrating-icon/. Retrieved 28 March 2017.
- ↑ "Otudeko Bags Business Person Of The Year Award". Uncova. December 19, 2015.
- ↑ Fick, David (2006). Africa: Continent of Economic Opportunity (First ed.). Johannesburg, South Africa: STE Publishers. pp. 63. ISBN 1-919855-44-0. https://books.google.com/books?id=GRMiBgAAQBAJ&pg=PA63. Retrieved 3 April 2017.
- ↑ 8.0 8.1 "Oba Otudeko: A self-made billionaire entrepreneur". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-15. Retrieved 2021-09-22.
- ↑ Akinmurele, Lolade (2024-08-19). "The business odyssey of Oba Otudeko: A journey of vision, valour and victory". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-08-20.
- ↑ "Oba Otudeko". Forbes.com.
- ↑ "Oba Otudeko Biography, Profile, CEO Honeywell Group". Recordsng.