Obi
Obì jẹ́ èso kàn nílé Yorùbá tí wọn fi máa ń ṣe, àlejò yálà ni ayẹyẹ tàbí láàrin ọ̀rẹ́ nígbà tí wón bá rírà won. Obì náà sì wà fún jíjẹ bóyá okunrin tàbí obìnrin, ọmọdé tàbí àgbà. Ṣùgbón òbí jẹ́ òun ìpanu tí àwọn àgbàlagbà, (arúgbó) má ní sábà jẹ jù. Obì yàtọ̀ sí tábà tàbí orógbó.