Obudu Cattle Ranch
Obudu Mountain Resort tí wọ́n tún ń pè ní (Obudu Cattle Ranch) ni ó jẹ́ ibi tí a dá sílẹ̀ fún àwọn ẹranko ní ìlú Obudu ní ìpínlẹ̀ Cross River State, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]
Obudu Mountain Resort Obudu Cattle Ranch | |
---|---|
Òkè kan ní Obudu | |
Coordinates: 6°22′N 9°22′E / 6.367°N 9.367°ECoordinates: 6°22′N 9°22′E / 6.367°N 9.367°E | |
Elevation | 1,600 m (5,200 ft) |
Àwọn ìtọkasí
àtúnṣe- ↑ Akpan, Ani (2007-04-02). "Nigeria launches $350 mln business, leisure resort" (in en). Reuters. https://www.reuters.com/article/idUSL02680939.