Ochai Young Agbaji (tí a bí ní April 20, 2000)[2] jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rè fún Utah Jazz èyí tó jẹ́ ti National Basketball Association (NBA). Gẹ́gẹ́ bí i ọ̀gá àgbà ní University of Kansas, wọ́n fún Agbaji lórúkọ, wọ́n sì dìbò fun ní ọdún 2022, gẹ́gẹ́ bí i Big 12 Player of the Year. Ó darí ẹgbẹ́ Jayhawks nínú ìdíje, títí wọ́n fi wọ ìpele tó kẹ́yìn, wọ́n sì sọ wọ́n ní Final Four Most Outstanding Player (MOP).

Ochai Agbaji
Agbaji in 2022
No. 30 – Utah Jazz
PositionShooting guard
LeagueNBA
Personal information
Born20 Oṣù Kẹrin 2000 (2000-04-20) (ọmọ ọdún 24)
Milwaukee, Wisconsin, U.S.
Listed height6 ft 5[1] in (1.96 m)
Listed weight215 lb (98 kg)
Career information
High schoolOak Park
(Kansas City, Missouri)
CollegeKansas (2018–2022)
NBA draft2022 / Round: 1 / Pick: 14k overall
Selected by the Cleveland Cavaliers
Pro playing career2022–present
Career history
2022–presentUtah Jazz
2022Salt Lake City Stars
Career highlights and awards

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Givony, Jonathan (June 24, 2022). "Ochai Agbaji Stats, News, Bio". ESPN. Retrieved June 24, 2022. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named tait_12112019