Octave Mirbeau (February 16, 1848 in Trévières, Calvados - February 16, 1917) je ara Fransi oniroyin, alagbewo iseona, olukowe irinajo, oniweroyin, onitan-enu, ati akoere oriitage. Ninu awon iwe re niwonyi : Le Calvaire (1886), L'Abbé Jules (1888), Sébastien Roch (1890), Le Jardin des supplices (1899), Le Journal d'une femme de chambre (1900), Les affaires sont les affaires (1903), La 628-E8 (1907), Le Foyer (1908), Dingo (1913).

Octave Mirbeau
Ọjọ́ ìbí(1848-02-16)16 Oṣù Kejì 1848
Trévières, France
Ọjọ́ aláìsí16 February 1917(1917-02-16) (ọmọ ọdún 69)
Paris, France
Iṣẹ́Novelist, Playwright
Notable worksLe Journal d'une femme de chambre (1900)
Les affaires sont les affaires (1903)