Octavia Butler
Octavia Estelle Butler (June 22, 1947 – February 24, 2006) je ara Amerika olukowe itan-aroso sayensi. O gba ebun Hugo ati Nebula. Ni 1995, o di olukowe itan aroso sayensi akoko to gba Igbowo MacArthur.[1]
Octavia E. Butler | |
---|---|
Butler signing a copy of Fledgling | |
Iṣẹ́ | Novelist |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United States |
Ìgbà | 1970s–2000s |
Genre | Science fiction |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Crossley, Robert (2003). "Critical Essay". Kindred: 25th Anniversary Edition. Boston: Beacon Press. p. 273.