Odò ìṣàn Ikogòsì
Odò ìṣàn Ikogòsì jẹ́ ọgbà kan tí àwọn olùbẹ̀wò sí ibi ìgbafẹ́ ma ń lọ láti fúnra wọn ní ìsinmi àti ìgbafẹ́. Odò ìṣàn Ikogòsì yí wà ní ìlú Ẹ̀rìjiyàn ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Nínú ọgbà ìgbafẹ́ yí, ó jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu wípé omi Lílèọ́ wọ́rọ́ àti omi tútù ti pàdé tí wọn kò si díra wọn lọ́wọ́. Èyí mú kí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn ó fẹ́ láti máa lọ gbàgànẹ́ níbi tí ó jẹ́ ayéẹ̀ mánigbàgbé. [2][3] [4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Redeveloped Ikogosi Resort: Revolutionising revenue generation in Ekiti". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Retrieved 1 March 2015.
- ↑ "Ikogosi: Resort comes alive in Ekiti". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 10 March 2015. Retrieved 1 March 2015.
- ↑ "Awesome Ikogosi Warm Springs Resort, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 1 March 2015.
- ↑ "Ikogosi warm spring: Nature’s gift to mankind". Vanguard News. Retrieved 1 March 2015.