Odò Bẹ́núé

Odò Benue jẹ́ odò tó ṣàn wọ odò Ọya. Odò yii gun to ìwòn ogóje kìlómítà bẹẹ si ni o rọrùn fún ọkọ̀ ojú omi lati gba a kọjá ni àkókò ẹ̀ẹ̀rùn. Nítorí ìdí èyí, Odò Bẹ́núé jẹ́ ọ̀nà ìrìnà ọkọ̀ tí o ṣe pàtàkì sí gbogbo àwọn agbègbè ti odò yii ṣan gba.

Benue SE Yola.jpg

ItokasiÀtúnṣe