Odò Congo River, tí àwọn ènìyàn mọ̀ tẹ́lẹ̀rí sí Odò Zaire, ní odò kejì tí ó gùn jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà, odò Nile nìkan ni ó kéré jùlọ. Ó tún wà lára àwọn odò tí ó tóbi jùlọ ní àgbáyé. Òun ni odò tí ó jìn jùlọ ní àgbáyé, jíjìn rẹ̀ tó ìwọ̀n ẹsẹ̀ okòó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́rin(720).[1] Gígùn odò Congo tó 4,370 km (2,715 mi).

Odò Congo
MouthAtlantic Ocean
Length4,700 km (2,900 mi)
Àwòrán odò Congo

Orúkọ àtúnṣe

Orúkọ odò náà, Congo/Kongo wá láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn Kongo tí wọ́n ti fi gúúsù etí odò náà ṣe ilé rí. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ àwọn ẹ̀yà tí ó ń gbé ibẹ̀ yìí sí "Esikongo".[2]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Oberg, Kevin (July 2008). "Discharge and Other Hydraulic Measurements for Characterizing the Hydraulics of Lower Congo River, July 2008" (PDF). U.S. Geological Survey. Archived from the original (PDF) on 2011-10-15. Retrieved 2012-03-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Anderson, David (2000). Africa's Urban Past. p. 79. ISBN 9780852557617. https://books.google.com/books?id=0IwMwBVfr0sC&pg=PA79. Retrieved 2017-05-04.