Ofe ujuju
Ìwé-alàyé[ìdá]
Ọbẹ̀ Ofe Ujuju jẹ́ ọkan lára àwọn ọbẹ̀ tí a lè bá pàdé ní apá Gúúsù ní orílé èdè Nàìjíríà. Ọbẹ yìí jẹ́ ọba kàn tí o gbajúmọ̀ jùlọ ní àárín àwọn Ika àti Agbor ní Ìpínlè Delta.[1]
Àwọn ohun tí á fi máa ń se obẹ̀ yìí ní: ẹran, ẹja, Ata dúdú, Mayo àti èyí tí o jẹ́ Olórí èròjà ẹ̀fọ́ tí wọn á má pẹ̀ ní Èwe Ujuji àti iyọ̀.[2]
Other foods
àtúnṣeA lè fí ọbẹ̀ Ofe Ujuju jẹ́ Ẹ̀bà, Fùfu, Sẹ́mó àti Iyán.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ oguntayo, gbenga (2021-12-28). "Native delicacy from Delta State (Ofè Ujuju)". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30.
- ↑ 2.0 2.1 Ashimedua (2021-08-07). "Native delicacy from Delta State (Ofè Ujuju)". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30.