Ohrigstad Dam
Àdàkọ:Infobox dam Ohrigstad Dam jẹ́ irú dam tí ó kún fún òkúta tí ó súmọ́ Ohrigstad ní Mpumalanga, South Africa. Wọ́n ṣẹ̀dá ẹ̀ ní ọdún 1955 àti pé ó maá ń ran àwọn ewéko lọ́wọ́ láti dàgbà sókè. Ewu rẹ̀ wà ní ipò gíga (3).
Àwọn Ìtọ́kasí