Epo jẹ́ asàn ni ìgbónásí àyíká towopo, tó lé jẹ́ sise bóyá láti inú alumoni haidrokarboni tàbí láti inú ọ̀gbìn tàbí láti inú fifunte àwọn kòkò ogbin, be si ni pe awon epo ko se dapo mo omi.

Ẹyìn síse
Ìgò epo olifu fún oúnjẹ.
Ọ̀pọ̀ gbogbogbo triglykeridi tó wà nínú àwọn epo ewebẹ̀ àti ọ̀rá ẹranko
Epo moto talasopapo
Epo Pupa nínú abọ́