Oju jẹ́ ẹ̀yà ara tí ẹranko àti ènìyàn ń lò láti ríran, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ gbogbo ẹranko ló ní ojú (ṣùgbọ́n àwọn ẹranko kan wà tí kò lójú) [1] Fún eniyan àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko, àwòrán tí ojú bárí á lọ sí ọpọlọ, ọpọlọ á sì túnmọ̀ àwòrán náà. Ènìyàn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹranko ní ojú méji, àwọn ẹranko inú odò tí a tún ń pè ní "copepods" ní ojú kan [2], àwọn ẹranko mìíràn ní ojú mẹ́ta , àwọn mìíràn ní mẹ́rin. Ìjàm̀bá sí ojú le fa àìríran tàbí ìṣòro pẹ̀lú ìan rírí[3]

Ojú
Schematic diagram of the human eye en.svg
Schematic diagram of the vertebrate eye.
Krilleyekils.jpg
Compound eye of Antarctic krill
Oju eniyan.

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. Mangan, Tom. "Animal Eyes". All About Vision. Retrieved 2022-03-06. 
  2. "Introduction to copepods". Nobanis. Retrieved 2022-03-06. 
  3. "what animal has 3 eyes". Lisbdnet.com. 2022-01-02. Retrieved 2022-03-06.